Òwe 12:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọ̀rọ̀ téèyàn sọ láìronú dà bí ìgbà tí idà gúnni,Àmọ́ ahọ́n ọlọ́gbọ́n ń woni sàn.+ Òwe 16:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀rọ̀ òdodo jẹ́ ìdùnnú àwọn ọba. Wọ́n fẹ́ràn ẹni tó bá ń sọ òótọ́.+