Àìsáyà 65:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, màá yàn yín fún idà,+Gbogbo yín sì máa tẹrí ba kí wọ́n lè pa yín,+Torí mo pè, àmọ́ ẹ ò dáhùn,Mo sọ̀rọ̀, àmọ́ ẹ ò fetí sílẹ̀;+Ẹ̀ ń ṣe ohun tó burú lójú mi ṣáá,Ẹ sì yan ohun tí inú mi ò dùn sí.”+
12 Torí náà, màá yàn yín fún idà,+Gbogbo yín sì máa tẹrí ba kí wọ́n lè pa yín,+Torí mo pè, àmọ́ ẹ ò dáhùn,Mo sọ̀rọ̀, àmọ́ ẹ ò fetí sílẹ̀;+Ẹ̀ ń ṣe ohun tó burú lójú mi ṣáá,Ẹ sì yan ohun tí inú mi ò dùn sí.”+