Òwe 28:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹni tó bá ń rìn láìlẹ́bi ni a ó gbà là,+Àmọ́ ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ wọ́ yóò ṣubú lójijì.+