Òwe 14:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Òdodo máa ń gbé orílẹ̀-èdè lékè,+Àmọ́ ẹ̀ṣẹ̀ máa ń kó ìtìjú bá orílẹ̀-èdè.