Òwe 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Láìsí ìfinúkonú,* èrò á dasán,Àmọ́ nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ agbani-nímọ̀ràn,* àṣeyọrí á wà.+ Òwe 20:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìmọ̀ràn* máa ń jẹ́ kí ohun téèyàn fẹ́ ṣe yọrí sí rere,*+Ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n sì ni kí o fi ja ogun rẹ.+ Òwe 24:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n ni kí o fi ja ogun rẹ,+Nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ agbani-nímọ̀ràn,* ìṣẹ́gun* á wà.+
18 Ìmọ̀ràn* máa ń jẹ́ kí ohun téèyàn fẹ́ ṣe yọrí sí rere,*+Ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n sì ni kí o fi ja ogun rẹ.+