Òwe 24:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọgbọ́n la fi ń gbé ilé* ró,+Òye sì la fi ń fìdí rẹ̀ múlẹ̀. Mátíù 7:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 “Torí náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tó sì ṣe é máa dà bí ọkùnrin kan tó ní òye, tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí àpáta.+ 25 Òjò sì rọ̀, omi kún àkúnya, ìjì sì fẹ́ lu ilé náà, àmọ́ kò wó, torí pé orí àpáta ni ìpìlẹ̀ rẹ̀ wà.
24 “Torí náà, gbogbo ẹni tó gbọ́ ọ̀rọ̀ mi yìí, tó sì ṣe é máa dà bí ọkùnrin kan tó ní òye, tó kọ́ ilé rẹ̀ sórí àpáta.+ 25 Òjò sì rọ̀, omi kún àkúnya, ìjì sì fẹ́ lu ilé náà, àmọ́ kò wó, torí pé orí àpáta ni ìpìlẹ̀ rẹ̀ wà.