ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 41:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Ni Fáráò bá sọ fún Jósẹ́fù pé: “Níwọ̀n bó ti jẹ́ pé Ọlọ́run ló jẹ́ kí o mọ gbogbo èyí, kò sí ẹni tó lóye, tó sì jẹ́ ọlọ́gbọ́n bíi tìẹ.

  • 1 Sámúẹ́lì 16:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ọ̀kan lára àwọn ẹmẹ̀wà* sọ pé: “Wò ó! Mo ti rí bí ọ̀kan lára àwọn ọmọ Jésè ará Bẹ́tílẹ́hẹ́mù ṣe ń ta háàpù dáadáa, onígboyà ni, jagunjagun tó lákíkanjú sì ni.+ Ó mọ̀rọ̀ọ́ sọ, ó rẹwà,+ Jèhófà sì wà pẹ̀lú rẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́