1 Pétérù 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí “ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ràn ìgbésí ayé rẹ̀, tó sì fẹ́ ẹ̀mí gígùn gbọ́dọ̀ ṣọ́ ahọ́n rẹ̀ kó má bàa sọ ohun búburú,+ kó má sì fi ètè rẹ̀ ṣẹ̀tàn.
10 Torí “ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ràn ìgbésí ayé rẹ̀, tó sì fẹ́ ẹ̀mí gígùn gbọ́dọ̀ ṣọ́ ahọ́n rẹ̀ kó má bàa sọ ohun búburú,+ kó má sì fi ètè rẹ̀ ṣẹ̀tàn.