-
Jẹ́nẹ́sísì 39:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Jósẹ́fù máa ń rí ojúure rẹ̀, ó sì di ìránṣẹ́ Pọ́tífárì fúnra rẹ̀. Ó wá fi ṣe olórí ilé rẹ̀, ó sì ní kó máa bójú tó gbogbo ohun ìní òun.
-
-
1 Àwọn Ọba 11:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ọkùnrin tó dáńgájíá ni Jèróbóámù. Nígbà tí Sólómọ́nì rí i pé ọ̀dọ́kùnrin náà jẹ́ òṣìṣẹ́ kára, ó fi í ṣe alábòójútó+ gbogbo àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ọ̀ranyàn ní ilé Jósẹ́fù.
-