Òwe 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ọ̀rọ̀ bá ti pọ̀, àṣìṣe ò ní ṣàì wáyé,+Àmọ́ ẹni tó bá ń ṣọ́ ẹnu rẹ̀ á máa fi ọgbọ́n hùwà.+ Mátíù 12:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Mò ń sọ fún yín pé ní Ọjọ́ Ìdájọ́, àwọn èèyàn máa jíhìn+ gbogbo ọ̀rọ̀ tí kò wúlò tí wọ́n sọ;