Ìṣe 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà tí wọ́n rí bí ọ̀rọ̀ ṣe dá lẹ́nu Pétérù àti Jòhánù,* tí wọ́n sì mọ̀ pé wọn ò kàwé* àti pé wọ́n jẹ́ gbáàtúù,+ ẹnu yà wọ́n gan-an. Wọ́n wá rántí pé wọ́n ti máa ń wà pẹ̀lú Jésù.+
13 Nígbà tí wọ́n rí bí ọ̀rọ̀ ṣe dá lẹ́nu Pétérù àti Jòhánù,* tí wọ́n sì mọ̀ pé wọn ò kàwé* àti pé wọ́n jẹ́ gbáàtúù,+ ẹnu yà wọ́n gan-an. Wọ́n wá rántí pé wọ́n ti máa ń wà pẹ̀lú Jésù.+