Róòmù 2:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìpọ́njú àti wàhálà yóò wà lórí gbogbo ẹni* tó ń ṣe ohun aṣeniléṣe, lórí Júù lákọ̀ọ́kọ́ àti lórí Gíríìkì pẹ̀lú; 10 àmọ́ ògo àti ọlá àti àlàáfíà yóò wà fún gbogbo ẹni tó ń ṣe rere, fún Júù lákọ̀ọ́kọ́ + àti fún Gíríìkì pẹ̀lú.+
9 Ìpọ́njú àti wàhálà yóò wà lórí gbogbo ẹni* tó ń ṣe ohun aṣeniléṣe, lórí Júù lákọ̀ọ́kọ́ àti lórí Gíríìkì pẹ̀lú; 10 àmọ́ ògo àti ọlá àti àlàáfíà yóò wà fún gbogbo ẹni tó ń ṣe rere, fún Júù lákọ̀ọ́kọ́ + àti fún Gíríìkì pẹ̀lú.+