Fílípì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ohun tí mò ń gbà ládùúrà ni pé kí ìfẹ́ yín lè túbọ̀ pọ̀ gidigidi,+ kí ẹ sì ní ìmọ̀ tó péye+ àti òye tó kún rẹ́rẹ́;+
9 Ohun tí mò ń gbà ládùúrà ni pé kí ìfẹ́ yín lè túbọ̀ pọ̀ gidigidi,+ kí ẹ sì ní ìmọ̀ tó péye+ àti òye tó kún rẹ́rẹ́;+