ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 2:22-25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Élì ti darúgbó gan-an, àmọ́ ó ti gbọ́ gbogbo ohun tí àwọn ọmọ rẹ̀ ń ṣe+ sí gbogbo Ísírẹ́lì àti bí wọ́n ṣe ń bá àwọn obìnrin tó ń sìn ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé sùn.+ 23 Ó sì máa ń sọ fún wọn pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń ṣe gbogbo nǹkan yìí? Ohun tí mò ń gbọ́ nípa yín látọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn kò dáa. 24 Kò dáa bẹ́ẹ̀, ẹ̀yin ọmọ mi, ìròyìn tí mò ń gbọ́ tí wọ́n ń sọ láàárín àwọn èèyàn Jèhófà kò dáa. 25 Bí èèyàn bá ṣẹ èèyàn bíi tirẹ̀, ẹnì kan lè bá a bẹ Jèhófà;* àmọ́ tó bá jẹ́ pé Jèhófà ni èèyàn ṣẹ̀,+ ta ló máa gbàdúrà fún un?” Ṣùgbọ́n wọn kò fetí sí bàbá wọn, nítorí pé Jèhófà ti pinnu láti pa wọ́n.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́