-
Léfítíkù 26:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “‘Tí ẹ bá ṣì ń kẹ̀yìn sí mi, tí ẹ ò sì fetí sí mi, ṣe ni màá fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ yín jẹ yín ní ìlọ́po méje.
-
-
Òwe 1:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Nítorí ìwà àìníjàánu àwọn aláìmọ̀kan ni yóò pa wọ́n,
Àìka-nǹkan-sí àwọn òmùgọ̀ ni yóò sì pa wọ́n run.
-