Òwe 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹni tó bá ń tọ́ afiniṣẹ̀sín sọ́nà ń wá àbùkù,+Ẹni tó bá sì ń bá ẹni burúkú wí yóò rí ìbànújẹ́. Jòhánù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń hùwà burúkú kórìíra ìmọ́lẹ̀, kì í sì í wá sínú ìmọ́lẹ̀, kí a má bàa dá àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́bi.* Jòhánù 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ayé ò ní ìdí kankan láti kórìíra yín, àmọ́ ó kórìíra mi, torí mò ń jẹ́rìí nípa rẹ̀ pé àwọn iṣẹ́ rẹ̀ burú.+
20 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń hùwà burúkú kórìíra ìmọ́lẹ̀, kì í sì í wá sínú ìmọ́lẹ̀, kí a má bàa dá àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́bi.*
7 Ayé ò ní ìdí kankan láti kórìíra yín, àmọ́ ó kórìíra mi, torí mò ń jẹ́rìí nípa rẹ̀ pé àwọn iṣẹ́ rẹ̀ burú.+