Sáàmù 41:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní tèmi, o ti dì mí mú nítorí ìwà títọ́ mi;+Wàá fi mí sí iwájú rẹ títí láé.+ Òwe 28:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹni tó bá ń rìn láìlẹ́bi ni a ó gbà là,+Àmọ́ ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ wọ́ yóò ṣubú lójijì.+