Òwe 8:35, 36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Nítorí ẹni tó bá rí mi yóò rí ìyè,+Yóò sì rí ìtẹ́wọ́gbà Jèhófà. 36 Àmọ́ ẹni tó bá pa mí tì, ara* rẹ̀ ló ń ṣe,Àwọn tó sì kórìíra mi fẹ́ràn ikú.”+
35 Nítorí ẹni tó bá rí mi yóò rí ìyè,+Yóò sì rí ìtẹ́wọ́gbà Jèhófà. 36 Àmọ́ ẹni tó bá pa mí tì, ara* rẹ̀ ló ń ṣe,Àwọn tó sì kórìíra mi fẹ́ràn ikú.”+