-
1 Sámúẹ́lì 15:13, 14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Níkẹyìn, Sámúẹ́lì dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, Sọ́ọ̀lù sì sọ fún un pé: “Kí Jèhófà bù kún ọ. Mo ti ṣe ohun tí Jèhófà sọ.” 14 Àmọ́ Sámúẹ́lì sọ pé: “Kí wá ni ohùn agbo ẹran tó ń dún yìí àti ohùn ọ̀wọ́ ẹran tí mò ń gbọ́ yìí?”+
-