Ìṣe 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Nítorí náà, ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì yí pa dà,+ kí Ọlọ́run lè pa àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́,+ kí àwọn àsìkò ìtura lè wá látọ̀dọ̀ Jèhófà fúnra rẹ̀,*
19 “Nítorí náà, ẹ ronú pìwà dà,+ kí ẹ sì yí pa dà,+ kí Ọlọ́run lè pa àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín rẹ́,+ kí àwọn àsìkò ìtura lè wá látọ̀dọ̀ Jèhófà fúnra rẹ̀,*