Jẹ́nẹ́sísì 31:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọlọ́run bá Lábánì ará Arémíà+ sọ̀rọ̀ lójú àlá ní òru,+ ó sọ fún un pé: “Ṣọ́ ohun tí o máa sọ fún Jékọ́bù, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.”*+ Ẹ́kísódù 34:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí màá lé àwọn orílẹ̀-èdè kúrò níwájú yín,+ màá sì mú kí ilẹ̀ yín fẹ̀, ilẹ̀ yín ò sì ní wọ ẹnikẹ́ni lójú nígbà tí ẹ bá ń gòkè lọ rí ojú Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún.
24 Ọlọ́run bá Lábánì ará Arémíà+ sọ̀rọ̀ lójú àlá ní òru,+ ó sọ fún un pé: “Ṣọ́ ohun tí o máa sọ fún Jékọ́bù, ì báà jẹ́ rere tàbí búburú.”*+
24 Torí màá lé àwọn orílẹ̀-èdè kúrò níwájú yín,+ màá sì mú kí ilẹ̀ yín fẹ̀, ilẹ̀ yín ò sì ní wọ ẹnikẹ́ni lójú nígbà tí ẹ bá ń gòkè lọ rí ojú Jèhófà Ọlọ́run yín lẹ́ẹ̀mẹta lọ́dún.