ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 22:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ni ọba bá sọ fún àwọn ẹ̀ṣọ́* tó dúró yí i ká pé: “Ẹ lọ pa àwọn àlùfáà Jèhófà, torí wọ́n ti gbè sẹ́yìn Dáfídì! Wọ́n mọ̀ pé ńṣe ló sá, wọn ò sì sọ fún mi!” Ṣùgbọ́n àwọn ìránṣẹ́ ọba kò fẹ́ gbé ọwọ́ wọn sókè láti pa àwọn àlùfáà Jèhófà. 18 Ìgbà náà ni ọba sọ fún Dóẹ́gì+ pé: “Ìwọ, lọ pa àwọn àlùfáà náà!” Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Dóẹ́gì ọmọ Édómù+ lọ pa àwọn àlùfáà náà fúnra rẹ̀. Ọkùnrin márùnlélọ́gọ́rin (85) tó ń wọ éfódì+ tí a fi aṣọ ọ̀gbọ̀* ṣe ni ó pa lọ́jọ́ yẹn.

  • 1 Àwọn Ọba 2:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ìgbà náà ni wọ́n wá sọ fún Ọba Sólómọ́nì pé: “Jóábù ti sá lọ sínú àgọ́ Jèhófà, ó sì wà níbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ.” Torí náà, Sólómọ́nì rán Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà pé: “Lọ pa á!”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́