Jémíìsì 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí ibikíbi tí wọ́n bá ti ń jowú tí wọ́n sì ń fa ọ̀rọ̀,* ìdàrúdàpọ̀ àti gbogbo nǹkan burúkú máa ń wà níbẹ̀.+
16 Torí ibikíbi tí wọ́n bá ti ń jowú tí wọ́n sì ń fa ọ̀rọ̀,* ìdàrúdàpọ̀ àti gbogbo nǹkan burúkú máa ń wà níbẹ̀.+