Òwe 15:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ó sàn kéèyàn ní díẹ̀, kó sì bẹ̀rù Jèhófà+Ju kó ní ọ̀pọ̀ ọrọ̀ pẹ̀lú àníyàn.*+ 17 Oúnjẹ tí a fi nǹkan ọ̀gbìn sè níbi tí ìfẹ́ wà+Sàn ju akọ màlúù àbọ́sanra* níbi tí ìkórìíra wà.+ Òwe 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó sàn láti máa gbé ní igun òrùléJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* gbé inú ilé kan náà.+ Òwe 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sàn láti máa gbé ní aginjùJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* àti oníkanra gbé.+
16 Ó sàn kéèyàn ní díẹ̀, kó sì bẹ̀rù Jèhófà+Ju kó ní ọ̀pọ̀ ọrọ̀ pẹ̀lú àníyàn.*+ 17 Oúnjẹ tí a fi nǹkan ọ̀gbìn sè níbi tí ìfẹ́ wà+Sàn ju akọ màlúù àbọ́sanra* níbi tí ìkórìíra wà.+