Òwe 27:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Bí ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ ṣe wà fún fàdákà, tí iná ìléru sì wà fún wúrà,+Bẹ́ẹ̀ ni ìyìn tí ẹnì kan gbà ṣe ń dán an wò.*
21 Bí ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ ṣe wà fún fàdákà, tí iná ìléru sì wà fún wúrà,+Bẹ́ẹ̀ ni ìyìn tí ẹnì kan gbà ṣe ń dán an wò.*