Òwe 18:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà tí wọ́n ṣe tán láti ṣe ara wọn níkà,+Àmọ́ ọ̀rẹ́ kan wà tó ń fà mọ́ni ju ọmọ ìyá lọ.+ Jòhánù 15:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kò sí ẹni tí ìfẹ́ rẹ̀ ju èyí lọ, pé kí ẹnì kan fi ẹ̀mí* rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀.+
24 Àwọn ọ̀rẹ́ kan wà tí wọ́n ṣe tán láti ṣe ara wọn níkà,+Àmọ́ ọ̀rẹ́ kan wà tó ń fà mọ́ni ju ọmọ ìyá lọ.+