26 Mo wá rí i pé: Ohun tó korò ju ikú lọ ni obìnrin tó dà bí àwọ̀n ọlọ́dẹ, tí ọkàn rẹ̀ dà bí àwọ̀n ńlá, tí ọwọ́ rẹ̀ sì dà bíi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀. Ẹni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ á bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀,+ àmọ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ á kó sọ́wọ́ rẹ̀.+
15 Ìta ni àwọn ajá* wà àti àwọn tó ń bá ẹ̀mí lò àti àwọn oníṣekúṣe* àti àwọn apààyàn àti àwọn abọ̀rìṣà àti gbogbo àwọn tó fẹ́ràn irọ́, tí wọ́n sì ń parọ́.’+