Jẹ́nẹ́sísì 27:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ṣùgbọ́n Ísọ̀ di Jékọ́bù sínú torí pé bàbá rẹ̀ ti súre fún un,+ Ísọ̀ sì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Ọjọ́ tí a máa ṣọ̀fọ̀ bàbá mi ti ń sún mọ́lé.+ Lẹ́yìn náà, ṣe ni màá pa Jékọ́bù àbúrò mi.” 2 Sámúẹ́lì 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ábúsálómù kò bá Ámínónì sọ nǹkan kan, ì báà jẹ́ búburú tàbí rere; nítorí Ábúsálómù kórìíra+ Ámínónì torí pé ó ti kó ẹ̀gàn bá Támárì+ àbúrò rẹ̀.
41 Ṣùgbọ́n Ísọ̀ di Jékọ́bù sínú torí pé bàbá rẹ̀ ti súre fún un,+ Ísọ̀ sì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Ọjọ́ tí a máa ṣọ̀fọ̀ bàbá mi ti ń sún mọ́lé.+ Lẹ́yìn náà, ṣe ni màá pa Jékọ́bù àbúrò mi.”
22 Ábúsálómù kò bá Ámínónì sọ nǹkan kan, ì báà jẹ́ búburú tàbí rere; nítorí Ábúsálómù kórìíra+ Ámínónì torí pé ó ti kó ẹ̀gàn bá Támárì+ àbúrò rẹ̀.