Oníwàásù 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọ̀rọ̀ ẹnu ọlọ́gbọ́n ń mú ire wá,+ àmọ́ ètè òmùgọ̀ ń fa ìparun rẹ̀.+