Òwe 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ó sàn kéèyàn ní díẹ̀, kó sì bẹ̀rù Jèhófà+Ju kó ní ọ̀pọ̀ ọrọ̀ pẹ̀lú àníyàn.*+ Jémíìsì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n. Ṣebí àwọn tí aráyé kà sí tálákà ni Ọlọ́run yàn pé kí wọ́n jẹ́ ọlọ́rọ̀ nínú ìgbàgbọ́+ àti ajogún Ìjọba náà, èyí tó ṣèlérí fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀?+
5 Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n. Ṣebí àwọn tí aráyé kà sí tálákà ni Ọlọ́run yàn pé kí wọ́n jẹ́ ọlọ́rọ̀ nínú ìgbàgbọ́+ àti ajogún Ìjọba náà, èyí tó ṣèlérí fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀?+