-
2 Sámúẹ́lì 3:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Nítorí náà, Jóábù wọlé lọ bá ọba, ó sì sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Ábínérì wá sọ́dọ̀ rẹ. Kí ló dé tí o fi rán an lọ, tí o sì jẹ́ kí ó lọ bẹ́ẹ̀?
-
-
Òwe 30:21, 22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ohun mẹ́ta wà tó ń mú kí ayé mì jìgìjìgì,
Àní ohun mẹ́rin tí ayé kò lè fara dà:
22 Tí ẹrú bá di ọba,+
Tí òmùgọ̀ bá jẹun yó,
-
Oníwàásù 10:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Mo ti rí àwọn ìránṣẹ́ tó ń gun ẹṣin àmọ́ tí àwọn olórí ń fẹsẹ̀ rìn bí ìránṣẹ́.+
-
-
-