Òwe 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó sàn láti máa gbé ní igun òrùléJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* gbé inú ilé kan náà.+ Òwe 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sàn láti máa gbé ní aginjùJu kéèyàn máa bá aya tó jẹ́ oníjà* àti oníkanra gbé.+ Òwe 27:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Aya tó jẹ́ oníjà* dà bí òrùlé tó ń jò ṣùrùṣùrù lọ́jọ́ tí òjò ń rọ̀.+