Òwe 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Di ìbáwí mú; má ṣe jẹ́ kó lọ.+ Pa á mọ́, nítorí òun ni ẹ̀mí rẹ.+