Òwe 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọwọ́ tó dilẹ̀ ń sọni di òtòṣì,+Àmọ́ ọwọ́ tó ń ṣiṣẹ́ kára ń sọni di ọlọ́rọ̀.+