Òwe 28:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ẹni tó bá gbẹ́kẹ̀ lé ọkàn ara rẹ̀ jẹ́ òmùgọ̀,+Àmọ́ ẹni tó ń fi ọgbọ́n rìn yóò yè bọ́.+ Jeremáyà 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jèhófà, mo mọ̀ dáadáa pé ọ̀nà èèyàn kì í ṣe tirẹ̀. Àní kò sí ní ìkáwọ́ èèyàn tó ń rìn láti darí ìṣísẹ̀ ara rẹ̀.+ 1 Kọ́ríńtì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kí ẹnì kankan má tan ara rẹ̀ jẹ: Tí ẹnikẹ́ni nínú yín bá rò pé òun gbọ́n nínú ètò àwọn nǹkan yìí,* kí ó di òmùgọ̀, kí ó lè gbọ́n.
23 Jèhófà, mo mọ̀ dáadáa pé ọ̀nà èèyàn kì í ṣe tirẹ̀. Àní kò sí ní ìkáwọ́ èèyàn tó ń rìn láti darí ìṣísẹ̀ ara rẹ̀.+
18 Kí ẹnì kankan má tan ara rẹ̀ jẹ: Tí ẹnikẹ́ni nínú yín bá rò pé òun gbọ́n nínú ètò àwọn nǹkan yìí,* kí ó di òmùgọ̀, kí ó lè gbọ́n.