Òwe 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ọ̀pọ̀ nǹkan ni ọ̀lẹ ń fẹ́, síbẹ̀ kò* ní nǹkan kan,+Àmọ́ ẹni* tó ń ṣiṣẹ́ kára yóò ní ànító.*+