Òwe 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kọ́ ọlọ́gbọ́n, yóò sì gbọ́n sí i. + Kọ́ olódodo, yóò sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i. Òwe 19:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Gbá afiniṣẹ̀sín,+ kí aláìmọ̀kan lè ní àròjinlẹ̀,+Sì bá olóye wí, kí ìmọ̀ rẹ̀ lè pọ̀ sí i.+