Òwe 15:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọ̀pọ̀ ìṣúra ló wà nínú ilé olódodo,Àmọ́ èso* ẹni burúkú máa ń fa wàhálà bá a.+ Oníwàásù 5:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bákan náà, nígbà tí Ọlọ́run tòótọ́ bá fún ẹnì kan ní ọrọ̀ àti ohun ìní,+ tó sì jẹ́ kó lè gbádùn wọn, kí ẹni náà gba èrè* rẹ̀ kó sì máa yọ̀ nínú iṣẹ́ àṣekára rẹ̀. Ẹ̀bùn Ọlọ́run ni èyí.+
19 Bákan náà, nígbà tí Ọlọ́run tòótọ́ bá fún ẹnì kan ní ọrọ̀ àti ohun ìní,+ tó sì jẹ́ kó lè gbádùn wọn, kí ẹni náà gba èrè* rẹ̀ kó sì máa yọ̀ nínú iṣẹ́ àṣekára rẹ̀. Ẹ̀bùn Ọlọ́run ni èyí.+