ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 23:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Tí aláìní kan láàárín yín bá ní ẹjọ́, má ṣe yí ìdájọ́ rẹ̀ po.+

  • Émọ́sì 5:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Nítorí mo mọ bí ìdìtẹ̀* yín ṣe pọ̀ tó

      Àti bí ẹ̀ṣẹ̀ yín ṣe pọ̀ tó

      Ẹ̀ ń dààmú àwọn olódodo,

      Ẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,*

      Ẹ sì ń fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n ní ẹnubodè.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́