Òwe 6:1-3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ọmọ mi, tí o bá ti ṣe onídùúró* fún ọmọnìkejì rẹ,+Tí o bá ti bọ àjèjì lọ́wọ́,*+ 2 Tí ìlérí rẹ bá ti dẹkùn mú ọ,Tí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ bá ti mú ọ,+ 3 Ohun tí wàá ṣe nìyí, ọmọ mi, kí o lè gba ara rẹ sílẹ̀,Nítorí o ti kó sọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ: Lọ rẹ ara rẹ sílẹ̀, kí o sì tètè bẹ ọmọnìkejì rẹ.+
6 Ọmọ mi, tí o bá ti ṣe onídùúró* fún ọmọnìkejì rẹ,+Tí o bá ti bọ àjèjì lọ́wọ́,*+ 2 Tí ìlérí rẹ bá ti dẹkùn mú ọ,Tí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ bá ti mú ọ,+ 3 Ohun tí wàá ṣe nìyí, ọmọ mi, kí o lè gba ara rẹ sílẹ̀,Nítorí o ti kó sọ́wọ́ ọmọnìkejì rẹ: Lọ rẹ ara rẹ sílẹ̀, kí o sì tètè bẹ ọmọnìkejì rẹ.+