Ẹ́kísódù 22:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ opó tàbí ọmọ aláìníbaba* kankan.+ 23 Tí ẹ bá fìyà jẹ ẹ́ pẹ́nrẹ́n, tó sì ké pè mí, ó dájú pé màá gbọ́ igbe rẹ̀;+ Sáàmù 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́, o rí ìjàngbọ̀n àti ìdààmú. Ò ń wò ó, o sì gbé ìgbésẹ̀.+ Ọ̀dọ̀ rẹ ni àwọn tó rin àrìnfẹsẹ̀sí yíjú sí;+Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ ọmọ aláìníbaba.*+
22 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ fìyà jẹ opó tàbí ọmọ aláìníbaba* kankan.+ 23 Tí ẹ bá fìyà jẹ ẹ́ pẹ́nrẹ́n, tó sì ké pè mí, ó dájú pé màá gbọ́ igbe rẹ̀;+
14 Àmọ́, o rí ìjàngbọ̀n àti ìdààmú. Ò ń wò ó, o sì gbé ìgbésẹ̀.+ Ọ̀dọ̀ rẹ ni àwọn tó rin àrìnfẹsẹ̀sí yíjú sí;+Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ ọmọ aláìníbaba.*+