Ìfihàn 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “‘Gbogbo àwọn tí mo fẹ́ràn ni mò ń bá wí, tí mo sì ń tọ́ sọ́nà.+ Torí náà, jẹ́ onítara, kí o sì ronú pìwà dà.+
19 “‘Gbogbo àwọn tí mo fẹ́ràn ni mò ń bá wí, tí mo sì ń tọ́ sọ́nà.+ Torí náà, jẹ́ onítara, kí o sì ronú pìwà dà.+