Òwe 13:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìmọ́lẹ̀ àwọn olódodo mọ́lẹ̀ rekete,*+Àmọ́ fìtílà àwọn ẹni burúkú ni a ó pa.+