Òwe 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Òjíṣẹ́ burúkú máa ń kó sínú ìjàngbọ̀n,+Àmọ́ aṣojú tó jẹ́ olóòótọ́ ń mú ìwòsàn wá.+