-
Òwe 30:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àwọn eṣúṣú* ní ọmọbìnrin méjì tó ń ké pé, “Mú wá! Mú wá!”
Ohun mẹ́ta wà tí kì í ní ìtẹ́lọ́rùn,
Àní ohun mẹ́rin tí kì í sọ pé, “Ó tó!”
-