Òwe 23:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+ 1 Tímótì 6:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Sọ* fún àwọn ọlọ́rọ̀ inú ètò àwọn nǹkan yìí* pé kí wọ́n má ṣe gbéra ga,* kí wọ́n má sì gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ tí kò dáni lójú,+ àmọ́ lé Ọlọ́run, ẹni tó ń pèsè gbogbo ohun tí à ń gbádùn fún wa lọ́pọ̀ rẹpẹtẹ.+
4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+ Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.* 5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+
17 Sọ* fún àwọn ọlọ́rọ̀ inú ètò àwọn nǹkan yìí* pé kí wọ́n má ṣe gbéra ga,* kí wọ́n má sì gbẹ́kẹ̀ lé ọrọ̀ tí kò dáni lójú,+ àmọ́ lé Ọlọ́run, ẹni tó ń pèsè gbogbo ohun tí à ń gbádùn fún wa lọ́pọ̀ rẹpẹtẹ.+