-
Dáníẹ́lì 3:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò dá ọba lóhùn pé: “Nebukadinésárì, kò sídìí láti ṣàlàyé ohunkóhun fún ọ lórí ọ̀rọ̀ yìí. 17 Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ìwọ ọba, Ọlọ́run wa tí à ń sìn lè gbà wá sílẹ̀ kúrò nínú iná ìléru tó ń jó, ó sì lè gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ rẹ.+
-