Sáàmù 91:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọlọ́run sọ pé: “Nítorí ó nífẹ̀ẹ́ mi,* màá gbà á sílẹ̀.+ Màá dáàbò bò ó torí pé ó mọ* orúkọ mi.+