2 Sámúẹ́lì 8:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Dáfídì ń jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì,+ Dáfídì ń dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, ó sì ń ṣe òdodo+ sí gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀.+ Sáàmù 89:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Òdodo àti ìdájọ́ òdodo ni ìpìlẹ̀ ìtẹ́ rẹ;+Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ àti òtítọ́ dúró níwájú rẹ.+ Àìsáyà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí.
15 Dáfídì ń jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì,+ Dáfídì ń dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, ó sì ń ṣe òdodo+ sí gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀.+
7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí.