Òwe 14:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹni tí kì í tètè bínú ní ìjìnlẹ̀ òye,+Àmọ́ ẹni tí kò ní sùúrù ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.+